Lẹ̀hìn tí ẹ̀gbẹ oṣélù LES DÉMOCRATES tí rí iwé iwà déédé tía mọ si récépissé gba. Kí ní ki àwon ọmọ̀ ìlù tí wọn nífẹ̀ẹ̀ ẹgbẹ̀ yí o màà rétí lọjọ̀ọ̀ ìwàju ni tí ígboké gbodó ẹ̀gbẹ nà? Làtí rì idàhùn sí ìbééré yì nia ṣé pé Bàbàà wà Gafarí ADÉCHỌKAN. Àkọ̀wé àgbá ẹgbẹ̀ ná ni ẹ̀káá awon ọdọ̀ éré ìdàràyá atí éto ígbàfẹ.Ẹ̀ gbọ ọ̀rọ̀ lẹ̀nù won.
2,918 total views, 2 views today