PODCAST

HAj 2022:Imam Abdoul Jalili YESSOUFOU ti mọṣalaṣì n’la Aíjẹ̀do fùn ẹ̀kùn rẹrẹ alayé.

  • avril 13, 2022
  • 1 min read
HAj 2022:Imam Abdoul Jalili YESSOUFOU ti mọṣalaṣì n’la Aíjẹ̀do fùn ẹ̀kùn rẹrẹ alayé.

Latí igbá tí arùn gbẹmin-gbẹmin tíamọ sí Covid- 19 tí gbodé kàn, ko ṣééṣé fùn awon mùsúlumí orílẹ édé miran latí lọ si Aji ni ílẹ̀ Arébía. Lọdùn yi, íjọba ilẹ larùbáwa ṣí a’nfani yi sílẹ fùn miliọnù kan éniyan latí wa ṣé Ají. Ṣùgbon írù awon wo ni won maa jẹ̀ a’nfani yen̏?

Imam Djalil YÉSÙFÙ ti mọṣalaṣì n’la Aíjẹ̀do fùn ẹ̀kùn rẹrẹ alayé.

 830 total views,  1 views today

About Author

crystalnews

Laisser une réponse

Votre adresse e-mail ne sera pas publiée. Les champs obligatoires sont indiqués avec *

  • https://www.radioking.com/play/crystal-news