Image default

ÍṢỌKAN ỌMỌ YORÙBÁ BÉNIN dá awon olùkọ édé yorùbá lẹ̀kọ pẹlùù iranlọwọ ajọ Unesco.

Ecouter l'article
  • Gbàngan ipadé sainte Arnouarite ni íjọba ibilẹ̀ Abomey-Calavi ni awon olùkọ édé yorùbá to wa latí Ouassa-Pehunko, Bantẹ̀,Manigrí,Ouidah,Porto-Novo,Sakété,Pobẹ̀, Kétou atí bẹẹbẹẹ lọ̀ ti padé . Labẹẹ abojùto olùkọ agbà atí orí adé Dominique BADA tí ilé ẹ̀kọ giga pata-pata ijọba ibilẹ̀ Abomey-Calavi.Fun ọpọọ wakátí ni atí mùrá awon olùkọ édé yorùbá gbaradi fùn iṣẹ̀ íkọni lẹ̀kọ yi, lona to pégédé.A rọwa pé kia gbọ ọrọ lẹ̀nù baba wa John Olùṣọla IGUÉ awon ní alagá ẹgbẹ̀ íṣọkan ọmọ yorùbá ilẹ Bénin .

 326 total views,  2 views today

Articles Similaires

Laisser un commentaire

* En utilisant ce formulaire, vous acceptez le stockage et le traitement de vos données par ce site Web.