28 March 2024
Bénin Société

Jean KPOTON: alatotonù orìì ikanní tia mọ si web activiste nià tí ran ni ẹ̀won oṣù méjila gbako.

  • février 9, 2021
  • 1 min read
Jean KPOTON: alatotonù orìì ikanní tia mọ si web activiste nià tí ran ni ẹ̀won oṣù méjila gbako.

Àlagbà Jean KPOTON ikan làrá awon ọ̀mọ̀ orílẹ̀ édé Bénin tio fàrà mọ ọna igba ṣakoso ijọbà to wà lorìì àléfa nia tí ràn lẹ̀wọn oṣù méjilá gbako pẹ̀lùù ọgọrù méji owoo cfa gẹgẹ bii owo ítanran. Oyẹ̀ kiẹ mọ pé ẹ̀sùn tíà fí kan ọkùnrín na ni pé: o tùn ísọfùnni kàn to sọ nipàà pé arẹ orilẹ édé Bénin hàyá ọkọ ayọkẹlẹẹ̀ rẹ̀ fun ijọbà ni milliọnù mẹ̀fà owo cfa. Niwon bi kotí si ẹ̀rì kan pato to tí àsọjadé oríí ikanní yi lẹ̀hin, oti ṣé lodi si ofin loríí awon ohùn tàà sọ, tabi kọ safẹ̀fẹ̀ niyen. Àwon agbẹ̀jọroo rẹ̀ yoo há pẹ̀jọọ ko tẹ̀mi lọrùn bȉ? Ko sẹni léé jẹ̀ hun bayí. Oyẹ kiẹ mọ pé latí ọjọrù 13̏ oṣù ṣẹẹrẹ̀ ni won ti mu alagbà na, ki won o to jùù sọ̀gbà ẹ̀won ilùù Kùtọnù ni 18 oṣù ṣẹẹrẹ̀ ọdùn 2021̇.

 2,321 total views,  1 views today

About Author

crystalnews

Laisser une réponse

Votre adresse e-mail ne sera pas publiée. Les champs obligatoires sont indiqués avec *

  • https://www.radioking.com/play/crystal-news