PODCAST

Mister Ókéké: Kiní kia mọ nipa Ẹgbẹ̀” UFFAS-P “?

  • mars 4, 2022
  • 1 min read
Mister Ókéké: Kiní kia mọ nipa Ẹgbẹ̀” UFFAS-P “?
Ídagbá soké ilù Ajàṣẹ, tíí ṣé olù ilú Bẹnin, iṣẹ̀ kọwa ọmọ ilù yi nì. Abájọ ti won tí fì fídí ẹgbẹ kan kalẹ latí ọdùn 2011 tía mọ si UFFAS-P Iyen ni ikorajọpọ awon ọmọ ilù Ajáṣẹ̀ l'ọkùnrin l'obirín l'ọmọdé l'agba ati awon ololufẹẹ won. Ki wa ni won tí gbéṣé ninù ẹgbẹ̀ yí latí ọdùn yiwà; ki si ni gońgo ilépa ẹgbẹ̀ na lọjọ iwajù ? Awon ibééré yi ni baba wa Mamoudou Éyissẹ̀ wa idahùn si ninù ifomi jomi toró ọrọ tí won ṣi ańfani rẹ silẹ̀ fùn wa. Anthony ỌLABINTAN gẹgẹ bíí olootù éto👇🏿

 840 total views,  2 views today

About Author

crystalnews

Laisser une réponse

Votre adresse e-mail ne sera pas publiée. Les champs obligatoires sont indiqués avec *

  • https://www.radioking.com/play/crystal-news