Íbééré yí ni íyááfin atì mínísìta atíjọ; ẹsẹlẹn’si Sofiath ONIFADÉ BABAMOUSSA gbíyanjù latì mù ídahùn wa nipáárẹ. Éléyí, latí ran awon ọdọbírìn tí won n’nanga sinù ọran oṣélú ni ákùko tía wa yi
Ìyááfín n’dahùn ibééré Oootù : Anthony ỌLABINTAN O. tí iléṣẹ̀ asọ̀rọ ma gbésí orí íkannì Crystal- News .
Sofiath ONIFADÉ BABAMOUSSA