PODCAST

Óṣélù: Ífíhan awón olùgbégbá ibó 08/ 01 /2023 ní ẹ̀kùn 19ìẹm.

  • novembre 28, 2022
  • 1 min read
Óṣélù: Ífíhan awón olùgbégbá ibó 08/ 01 /2023 ní ẹ̀kùn 19ìẹm.

Ọjọ aíkù to kọjá yí ìyen 27 11 2022 ní awon aṣáájù ẹ̀gbẹ oṣélù MOELE Bénín ẹkùn kọkandilogùn yan latí fi awón olùgbégba ìbo ẹ̀ na han awon ará ílù.

Lòjù ẹ̀bi,ára atí ọrẹ̀ nia pé orùkọ̀ ikọọkan awon olùgbégba ibo na, latí wá fárà han.

Ohùn íwùrí gbáá ni fùn aṣáájù ẹ̀gbẹ̀ oṣélù MOELE Bénin tí ẹ̀kùn kọkandilogùn álàgbá atí onipo kiní Serge N.AHOUANSOU nínù alayé won.

Anthony O. LABINTAN lo ń jabọ ìṣẹ̀ latí ojùléṣẹ̀ Crystal News.

About Author

crystalnews

Laisser une réponse

Votre adresse e-mail ne sera pas publiée. Les champs obligatoires sont indiqués avec *

  • https://www.radioking.com/play/crystal-news